Home Orisirisi Liz Anjorin ati Tunde Kelani jo g’oke Arafa
Orisirisi - August 21, 2018

Liz Anjorin ati Tunde Kelani jo g’oke Arafa

download
Gbajugbaja onifiimu, Alagba Tunde Kelani, wa lara awon gbajumo ti won n sise Haaji lowolowo ni Mecca ati Medina.
Bakan naa ni onifiimu Yoruba miiran ti a mo si Liz Anjorin.
Ninu foto kan ti Anjorin gbe jade, a ri awon mejeeji nibi ti won ti n sise Haaji naa, ti won si n mura lati soko mo asetaani.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Àwọn òṣìṣẹ́, Shoprite, bẹ̀rẹ̀ ìfẹ̀hónúhàn káàkiri àwọn ìpínlẹ̀ kan ní Nàìjíríà.

Àwọn òṣìṣẹ́, Shoprite, bẹ̀rẹ̀ ìfẹ̀hónúhàn káàkiri àwọn ìpínlẹ̀ kan ní Nàìjíríà. Orẹ Òtítọ́…