Home Orisirisi Esin ko f’a’ja: Ooni ba awon Musulumi ki yidi ni Ife
Orisirisi - August 21, 2018

Esin ko f’a’ja: Ooni ba awon Musulumi ki yidi ni Ife

5b7c4a018ee335b7c4a018ee33
Nigba ti Ooni ti Ile-Ife, Oba Adeyeye Ogunwusi, so pe gbogbo esin ni oun n sin gege bi oba, awon kan ko mo oun ti Kabiyesi n so.
Oba Ogunwusi mu ileri re se lonii, nigba to darapo mo awon Musulumi, ti won si jo ki yidi ni Ife.
Awon foto kan ti won da sori Linda Ikeji so pupo ninu oro naa…

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Iléeṣé ológùn ti sìnkú àwọn akọni tó bá ìjàmbá ọkọ̀ Bàálù lọ ní Abuja

Iléeṣé ológùn ti sìnkú àwọn akọni tó bá ìjàmbá ọkọ̀ Bàálù lọ ní Abuja Ọrẹ Òtítọ́jù Àwáyé è…