Home LÁGBO ÀRÍYÁ Ayefele ba omokunrin je, o bu sekun gbagada!
LÁGBO ÀRÍYÁ - Orisirisi - August 21, 2018

Ayefele ba omokunrin je, o bu sekun gbagada!

images
Yoruba bo, won ni eni ti oro ko ba lo n pe ara re l’okunrin. Akorin pataki, Yinka Ayefele, lo le jeri si oro yi lowolowo yii.
Idi niyi ti o fi bu sekun gbagada ni Ibadan ni irole ana, nigba to n ba awon oniroyin soro lori bi ijoba Ipinle Oyo se iwo ile ise redio re.
O ni gbogbo iwe to ye ki oun gba ni oun gba lowo gege. O ni nigba ti wahala a o wole, a ko wole de, iyawo oun lo be Ajimobi lale ojo Satide. Ayefele ni Ajimobi so fun iyawo oun pe awon ko ni wo ile naa mo.
Koda, o ni Ajimobi fun iyawo oun ni nnkan alejo, eyi to je egberun dola kan – $1,000.
O ni eyi lo se ya oun lenu pupo nigba ti won tun gbe katapila de ni idaji Sunday.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Igboho àtàwọn adarí OPC bẹ Aarẹ Ọ̀nà Kakanfo ilẹ̀ Yoruba wò

Igboho àtàwọn adarí OPC bẹ Aarẹ Ọ̀nà Kakanfo ilẹ̀ Yoruba wò Ọrẹ Òtítọ́jù Aja-fẹtọọ’m…