Home Orisirisi Tiwa Savage soro lori ajosepo to wa laarin oun ati Wizkid
Orisirisi - August 20, 2018

Tiwa Savage soro lori ajosepo to wa laarin oun ati Wizkid

Gbogbo ohun ti won n so nipa emi ati Wizkid ni mo n gbo – Tiwa Savage
Akorin pataki, Tiwa Savage, ti so pe gbogbo oro ti awon eniyan kan n so nip ape oun ati Wizkid jo ni ajosepo ni oun n gbo.
O ni oun ko fesi le eyi nitori pe iru oro isokuso bee ti di baraku fun oun ni.
O ni nigba kan, won koko so pe oun ati Humblesmith n fe ara awon; o ni nigba to ya, won tun ni oun ati elomiran ni awon n se isekuse.tiwa-savage-wizkid
O ni iriri oun ninu ise alariya ti ko ohun pe kii se gbogbo oro ni oun maa fesi le.
Lori igbeyawo re pelu Teebilz, Tiwa Savage ni oro abele niyen, ti oun ko le maa so ni ita gbangba.
Inu iforowero kan pelu Soundcity ni o ti so awon oro yii.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Àwọn òṣìṣẹ́, Shoprite, bẹ̀rẹ̀ ìfẹ̀hónúhàn káàkiri àwọn ìpínlẹ̀ kan ní Nàìjíríà.

Àwọn òṣìṣẹ́, Shoprite, bẹ̀rẹ̀ ìfẹ̀hónúhàn káàkiri àwọn ìpínlẹ̀ kan ní Nàìjíríà. Orẹ Òtítọ́…