Atiku soro lori bi Ajumobi se wo ile Ayefele
Igbakeji Aare tele, Alhaji Atiku Abubakar, ti fie dun oka re han lori bi ijoba Ipinle Oyo se wo lara ile ise redio Fresh FM ni Ibadan, eyi to je ti Yinka Ayefele.
O ni o ye ki awon oniroyin ni aaye lati se ise won lai si idiwo.
Atiku ni ohun to dun oun nibe ju ni pe ile ise naa n pese atije atimu fun awon omo Naijiria kan. O ni idi niyi ti ko fi ye ki won wo o.
Nàìjíríà sì nílò Ọbásanjọ́ fún ẹkọ́, ọgbọ́n àti ìmọ̀ láti tukọ̀ orílẹ̀-èdè yìí- Buhari
Nàìjíríà sì nílò Ọbásanjọ́ fún ẹkọ́, ọgbọ́n àti ìmọ̀ láti tukọ̀ orílẹ̀-èdè yìí- Buhari Fẹ́…