Home LÁGBO ÀRÍYÁ Eniola Badmus ni oun ko le fẹ ọkunrin ti ẹnu re ba n run
LÁGBO ÀRÍYÁ - August 18, 2018

Eniola Badmus ni oun ko le fẹ ọkunrin ti ẹnu re ba n run

Imoran nla niyi fun awon okunrin ti won ba nifee lati sunmo onifiimu Eniola Badmus o. Eni to ba ti mo pe enu oun n run, tabi to ni oorun ara – eyi ti awon oloyinbo n pe ni mouth odour ati body odour – ki o ma sun mo o rara o.
O ti so pe gbogbo nnkan ni oun le mu mora lodo okunrin, sugbon oun ko le ba okunrin to ni oorun lenu lati orun wa ati eyi to ba ni body odour se papo.
O so eyi ninu ifirowanilenuwo kan to jade ninu iwe iroyin Punch.
Enila Badmus ko so pe eni to ba maa fe oun gbodo ni owo lowo tabua. Dipo bee, ofe ki o je kola-ko-sagbe, sugbon oye ati opolo re gbodo pe.
Laipe yii ni o so oro yii ninu iforowanilenuwo kan.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Mi ò gba owó oṣù fún ọdún mẹ́jọ mi gẹ́gẹ́ bíi gómìnà Ọ̀sun

Mi ò gba owó oṣù fún ọdún mẹ́jọ mi gẹ́gẹ́ bíi gómìnà Ọ̀sun Ọrẹ Òtítọ́jù Minisita ọrọ abẹle…