Home iroyin Iwonyi ni awon osise banki ti awon olopaa n wa lori esun jibiti N500m
iroyin - August 17, 2018

Iwonyi ni awon osise banki ti awon olopaa n wa lori esun jibiti N500m

683
Awon olopaa ti n wa awon osise banki mesan-an kan to jo pe won ti na papa bora.
Awon alase olopaa ni owo to je eedegbeta milionu naira – N500m – ni awon meseesan ji ni banki kan ti won ti n sise.
Won ko daruko banki naa.
Iwe ti awon olopaa gbe jade fihan pe obinrin kan ti oruko re n je Linda Chekwube wa lara awon eniyan naa.
Oruko won ni, Oshiojum Chibuzor Wilson, Juwon Faromoh, Akanaga Christian, Linda Chekwube, Matthew Akpan, Oluwasoji Ajetumobi, Nelson Omuzagha, Ogunlaja Ganiyu ati Adeyemi Omitogu

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Nàìjíríà sì nílò Ọbásanjọ́ fún ẹkọ́, ọgbọ́n àti ìmọ̀ láti tukọ̀ orílẹ̀-èdè yìí- Buhari

Nàìjíríà sì nílò Ọbásanjọ́ fún ẹkọ́, ọgbọ́n àti ìmọ̀ láti tukọ̀ orílẹ̀-èdè yìí- Buhari Fẹ́…