Home Orisirisi Funke Adesiyan di Alhaja betilai!
Orisirisi - August 17, 2018

Funke Adesiyan di Alhaja betilai!

Ojo ti e ba tun ti ri osere fiimu to n je Funke Adesiyan, e ma pe e loruko mo o.
‘Haja Betilai’ ni ki e ma ape e .
Bi a se n soro yii, Mecca ni Funke wa, ti oun naa n mura sile lati so oko mo asetaani.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Agbébọn tún jí akẹ́kọ̀ọ́bìnrin 317 gbé ní Zamfara

Agbébọn tún jí akẹ́kọ̀ọ́bìnrin 317 gbé ní Zamfara Orẹ Òtítọ́jù Egbìnrìn ọ̀tẹ̀ bí a ṣe ń pà…