Aregbesola fun awon onisese ni olude tiwon naa
Erongba awon elesin ibile Naijiria lati je pe awon naa ni olude gege bi awon elesin Musulumi ati Krisiteeni ti bere sii di amuse.
Ipinle Osun ni eyi ti waye, nibi ti ijoba Ogbeni Rauf Aregbesola ti fun awn elesin ibile ni olude ni ogunjo osu kejo – August twentieth – ni olude Ojo Isese.
Komisanna fun Eto Ile, Alagba Adebisi Obawale, lo kede eyi.
Igboho àtàwọn adarí OPC bẹ Aarẹ Ọ̀nà Kakanfo ilẹ̀ Yoruba wò
Igboho àtàwọn adarí OPC bẹ Aarẹ Ọ̀nà Kakanfo ilẹ̀ Yoruba wò Ọrẹ Òtítọ́jù Aja-fẹtọọ’m…