Home Orisirisi Ope o! Ajimobi ko tii wo ile Ayefele
Orisirisi - August 16, 2018

Ope o! Ajimobi ko tii wo ile Ayefele

Y29udGVudC9jb250ZW50L3lpbmthYXllZmVsZWJiYmYuanBnfDY2MA==
Bi o tile je pe ijoba Gomina Isiaka Abiola Ajimobi se ileri lanaa pe oun yoo wo ile nla ti akorin pataki, Yinka Ayefele, ko si adugbo Orita Challenge ni Ibadan lonii, ile naa si wa nibe bayii o.
Eyi umo sip e Ajimobi ko tii gbegi le ile naa.
Awuyewuye bere lati ojo merin seyin nigba ti ijoba so pe oun maa wo ile naa, nibi ti ile ise redio Ayefele ati ile ti won ti n po orin po (studio) wa.
Ijoba ni oun fe se eyi tori ibi ti Ayefele ko ile naa si ko ba ofin mu.
Sugbon Ayefele ni iro ni Gomina Ajimobi pa mo oun.
O ni ija oselu ni ijoba n ba oun ja.
O ni gbogbo iwe to ye ki oun gba lowo ijoba ni oun gba lori ile naa.
IROYIN OWURO gbo pe opo awon eniyan nla lo ti n ba Ayefele be Ajimobi lori oro naa.
Sugbon sa o, a ko mo ohun to le sele ki ile to su lonii, tori aseyiowu u ni ijoba.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Agbébọn tún jí akẹ́kọ̀ọ́bìnrin 317 gbé ní Zamfara

Agbébọn tún jí akẹ́kọ̀ọ́bìnrin 317 gbé ní Zamfara Orẹ Òtítọ́jù Egbìnrìn ọ̀tẹ̀ bí a ṣe ń pà…