Home LÁGBO ÀRÍYÁ Idi ti n ko fi se fiimu mo – Toyosi Arigbabuwo
LÁGBO ÀRÍYÁ - August 16, 2018

Idi ti n ko fi se fiimu mo – Toyosi Arigbabuwo

Agba osere tiata ati fiimu, Toyosi Arigbabuwo, ti so idi ti oun ko fi kopa ninu opolopo ere onise ati fiimu mo.
Opo eniyan ni enu ti n ya tele lori pe ibo ni okunrin na wa.
Sugbon okan lara awon oniroyin pataki pelu Nigerian Tribune, Alagba Tunde Busari, lo se alabapade re nibi igbeyawo kan to waye ni Ibadan.
Arigbabuwo, eni to maa n fie kun iyawo kewi, so pe logbologbo to n fi ise alariya, paapaa fiimu sise, lo le oun seyin.
O ni bi nnkan bat un senu rere pada ni Naijiria, oun si le pada soju opon.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Àwo̩n aké̩kò̩ó̩ WASCCE tó fi ìsekúse parí ìdánwò

Àwo̩n aké̩kò̩ó̩ WASCCE tó fi ìsekúse parí ìdánwò Yìnká Àlàbí O ma se o! Awo̩n ake̩ko̩o̩…