‘Ooni ko ni se igbeyawo pelu Tope Adesegun’.
Iroyin kan to hu jade lojo Satide pe Ooni Ife, Oba Adeyeye Ogunwusi, ti fe se igbeyawo pelu arabinrin kan ti oruko re n je Tope Adesegun ni a ti gbo pe kii se otito bayii.
Ninu atejade kan to wa lati aafin Ooni ni Ife, won ni ko si erongba Kankan lati se igbeyawo pelu Adesegun, ati pe bi Kabiyesi ba fe se igbeyawo, won yoo kede re fun gbogbo araye.
Tejade naa fi kun un pe awon igbese ti Ooni n gbe lati mu ki irepo ati ilosiwaju ba ile Yoruba ati Aafirika lapapo lo si je e logun bayii.
Igboho àtàwọn adarí OPC bẹ Aarẹ Ọ̀nà Kakanfo ilẹ̀ Yoruba wò
Igboho àtàwọn adarí OPC bẹ Aarẹ Ọ̀nà Kakanfo ilẹ̀ Yoruba wò Ọrẹ Òtítọ́jù Aja-fẹtọọ’m…