Home ERÉ ÌDÁRAYÁ Man City fi iya nla je Arsenal
ERÉ ÌDÁRAYÁ - August 12, 2018

Man City fi iya nla je Arsenal

Bi o tile je pe adari egbe agbaboolu Arsenal ni oludari tuntun, ti oruko re n je Unai Emeri, iya ajedunju ni won je ni irole oni o.
Won ti bere Premier League odun yii pelu omulemofo, tori Man City na won ni anabole.
Ninu idije akoko ti won gba lonii, Man City ni ami ayo meji, nigba ti Arsenal ko lee gba eyo Kankan wole.
Raheem Sterlin ati Bernado Silva lo rojo ayo naa sile Arsenal.
Eyi tumo si pe bi o tile je pe Arsene Wenger ti kuro ni egbe agbaboolu naa, nnkan ko tii se enu rere fun won.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Iléeṣé ológùn ti sìnkú àwọn akọni tó bá ìjàmbá ọkọ̀ Bàálù lọ ní Abuja

Iléeṣé ológùn ti sìnkú àwọn akọni tó bá ìjàmbá ọkọ̀ Bàálù lọ ní Abuja Ọrẹ Òtítọ́jù Àwáyé è…