Home iroyin O ma se o! Won fi oku agunbaniro mesan-an ranse si obi won
iroyin - August 11, 2018

O ma se o! Won fi oku agunbaniro mesan-an ranse si obi won

Awon ajo to n dari ise isinru ilu, iyen National Youths Serive Corps, ti fi oku awon agunbaniro mesan-an ti won ku sinu odo kan ni Taraba ranse si awon obi won kaakiri Naijiria o.
Ose to lo ni isele buruku naa waye ngba ti awon alaisi naa baa won akegbe won lo gbafe ni odo naa.
Lati seye fun won, awon NYSC gbe oku awon omo naa sinu posi ringindin, bi o tile je pe ekun si gbenu opo awon elegbe won.
Ki Olorun fori jin awon oloogbe naa. Ko Olorun tu awon obi won ninu. Ki Oba Oke o sib a wa dawo ibanuje ati ajalu bee duro.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Iléeṣé ológùn ti sìnkú àwọn akọni tó bá ìjàmbá ọkọ̀ Bàálù lọ ní Abuja

Iléeṣé ológùn ti sìnkú àwọn akọni tó bá ìjàmbá ọkọ̀ Bàálù lọ ní Abuja Ọrẹ Òtítọ́jù Àwáyé è…