Home Orisirisi O jo pe Ini Edo fe se igbeyawo miiran
Orisirisi - August 10, 2018

O jo pe Ini Edo fe se igbeyawo miiran


Esin kii da ni ka ma tun un gun. Owe yii jo ti osere fiimu oyinbo, Ini Edo, eni ti igbeyawo re akoko forin sanpon ni odun die seyin.
Inu opolopo ololufe re lo dun nigba ti oun ati Philip Ehiagwina se igbeyawo naa.
Sugbon kop e ti ituka fi de.
Sugbon Ini Edo ti n fu awon eniyan lara pe igbeyawo miiran n kanlekun.
Eyi ri be latari oruka igbeyawo – engagement ring – to gbe jade ninu foto re tuntun kan.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ààrẹ Buhari àti igbákejì rẹ̀, Yemi Osinbajo ti gba abrẹ́rẹ́ àjẹsáèra Kófíìdì-19.

Ààrẹ Buhari àti igbákejì rẹ̀, Yemi Osinbajo ti gba abrẹ́rẹ́ àjẹsáèra Kófíìdì-19. Ọrẹ Òtítọ…