Home iroyin Ise Olorun, awamaridii! Obinrin kan bi omo marun-un leekan soso!
iroyin - August 10, 2018

Ise Olorun, awamaridii! Obinrin kan bi omo marun-un leekan soso!

Olorun ti sise iyanu nla ninu aye arabinrin kan, Ifeoma Ogbonaya, bayii o. Oyun ti o ni fun bale re, Nwaka Ogbonaya, ibarun-un, iyen omo marun-un, lo fi bi.
Ile Iwosan Life International Hospital, ni Awka, ni o bimo naa si.
Opo eniyan lo da lo sibe ti won lo ba Ifeoma ati bale re yo.
Sugbon sa o, bi Nwaka se n dunnu naa ni eru n ba a, lori bi yoo se gbo bukaata lori awon omo naa.
O n ro awon ijoba ati awo eleyinju aanu miiran pe ki won wa ran oun lowo.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Nàìjíríà sì nílò Ọbásanjọ́ fún ẹkọ́, ọgbọ́n àti ìmọ̀ láti tukọ̀ orílẹ̀-èdè yìí- Buhari

Nàìjíríà sì nílò Ọbásanjọ́ fún ẹkọ́, ọgbọ́n àti ìmọ̀ láti tukọ̀ orílẹ̀-èdè yìí- Buhari Fẹ́…