Home LÁGBO ÀRÍYÁ Yinka Quadri rojo adura le Saheed Osupa lori
LÁGBO ÀRÍYÁ - August 9, 2018

Yinka Quadri rojo adura le Saheed Osupa lori


Agba osere Yinka Quadri naa ti darapo mo awon ti won ki Saheed Osupa ku oriire ti ojo ibi re o.
Ana Alaaruba ni Olorun fi odun kan miiran kun ojo ori Osupa, ti opolopo eniyan sib a a se ajoyo.
Nigba ti Yinka Quadri n soro lori eyi, o ni oun ba Osupa dupe gidi lowo Olorun, se aimoye ojo lo ti ro ti ile ti fimu.
O ni o je ohn idunnu pe inu alaafia ati owo tabua ni Osupa ti se ojo ibi miiran.
O ni olubori ati asegun (conqueror and winner) ni Osupa. Yinka Quadri naa wa gba a ni adura ki Olorun fi orin tuntun si enu olojo ibi naa.
Opo awon gbajumo osere bii Ronke Osodi Oke, Muyiwa Ademola Authentic ati Kabirah Kafidipe naa ni won ba Osupa dupe lowo Olorun.
Bi awon awo ti akorin fuji naa se wa n ki fun un, ni oun naa n ki fun awon awo re.
O dupe gidigidi lowo won.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Igboho àtàwọn adarí OPC bẹ Aarẹ Ọ̀nà Kakanfo ilẹ̀ Yoruba wò

Igboho àtàwọn adarí OPC bẹ Aarẹ Ọ̀nà Kakanfo ilẹ̀ Yoruba wò Ọrẹ Òtítọ́jù Aja-fẹtọọ’m…