Home Orisirisi Tinubu binu si Obasanjo
Orisirisi - August 9, 2018

Tinubu binu si Obasanjo

Ilu Akwa Ibom ni igba ti awon oloselu lo n gba Seneto Godswill Akpabio lalejo sinu egbe oselu APC ni orisiirisii oro ti jade.

Ibe ni Asiwaju Bola Ahmed Tinubu ti n salaye iru egbe ti APC je. O ni Aare Olusegun Obasanjo si n ko leta si Aare Buhari ni igba ti aye ti sun kuro ni aye leta.

O ni aye ti sun si ero ayelujara bii whatsapp, instagram, Facebook ati bee bee lo. Asiwaju ni ko le ya oun lemu ni igba ti ijoba PDP fi odun merindinlogun pin owo Naijiria. O ni egbe oselu ti awon o ki n se odaju. O ni ijoba tiwa-n-tiwa ni a wa, gbogbo ara ilu lo si ye ki o je anfaani naa.

Tinubu ni ki Alagba Obasanjo ye je “agbonrin esi”. O ni inu oun si dun si awon ti ko le fara da ijoba gbogbo ilu bi won se ” yo ese” kiakia.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Àwọn òṣìṣẹ́, Shoprite, bẹ̀rẹ̀ ìfẹ̀hónúhàn káàkiri àwọn ìpínlẹ̀ kan ní Nàìjíríà.

Àwọn òṣìṣẹ́, Shoprite, bẹ̀rẹ̀ ìfẹ̀hónúhàn káàkiri àwọn ìpínlẹ̀ kan ní Nàìjíríà. Orẹ Òtítọ́…