Home Orisirisi Ota bi ore ni Saraki tele – Lai Mohammed
Orisirisi - August 9, 2018

Ota bi ore ni Saraki tele – Lai Mohammed


Minisita fun Oro Iroyin ati Asa, Alhaji Lai Mohammed, tun ti digbo lu Aare Ile Igbimo Asofin Agba, Dokita Bukola Saraki, latari bi o se kuro ni egbe APC.
Lai Mohammed ni o dara fun APC bi Saraki se lo tori seku-seye, ota ile ati ota bi ore ni Saraki tele.
O ni nigba to wa ni APC, ifaseyin lo n mu ba egbe.
Lai Mohammed fi kun un pe eni to pe ara re ni omo egbe APC ko sise gidi fun egbe nile igbimo asofin, koda o ni Saraki gan-an ni kii je ki ife ijoba APC se.
O wa mu u da awon eniyan Kwara loju pe egbe APC yoo tubo ni aseyori nibe ni, bayii ti Saraki ti yose.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Nàìjíríà sì nílò Ọbásanjọ́ fún ẹkọ́, ọgbọ́n àti ìmọ̀ láti tukọ̀ orílẹ̀-èdè yìí- Buhari

Nàìjíríà sì nílò Ọbásanjọ́ fún ẹkọ́, ọgbọ́n àti ìmọ̀ láti tukọ̀ orílẹ̀-èdè yìí- Buhari Fẹ́…