Pe eniyan je alariya ko ni ki o ma sin Olorun – Jide Kosoko
Agba oje ninu ere onise, Alagba Jide Kosoko, ti gba gbogbo eniyan niyanju pe ninu gbogbo ohun ti won ba n se ki won maa ya ti Olorun soro.
O ni o se pataki ki won maa sin Olorun, ki won si duro deede.
Jide Kosoko ni paapaa awon to je alariya gbodo ranti pe gbogbo abebelube, ibe lo maa n be si, ko si si oke miiran leyin Olorun.
Nigba to n ba awon oniroyin soro lasiko eto ipejo adura kan, Jide Kosoko ni toun pelu ebi oun o, Olorun kan soso naa ni awon n sin ati pe oun kii fi ti Waidu sere.
Àwọn òṣìṣẹ́, Shoprite, bẹ̀rẹ̀ ìfẹ̀hónúhàn káàkiri àwọn ìpínlẹ̀ kan ní Nàìjíríà.
Àwọn òṣìṣẹ́, Shoprite, bẹ̀rẹ̀ ìfẹ̀hónúhàn káàkiri àwọn ìpínlẹ̀ kan ní Nàìjíríà. Orẹ Òtítọ́…