Home Ọ̀RỌ̀-ÒSÈLÚ Osinbajo fi ibinu le oludari otelemuye DSS danu!
Ọ̀RỌ̀-ÒSÈLÚ - August 7, 2018

Osinbajo fi ibinu le oludari otelemuye DSS danu!


Igbakeji Aare, Ojogbon Yemi Osinbajo, ti le Oga Agba awon otelemuye agbofinro DSS, Lawal Daura, danu.
Osinbajo, eni to n dele fun Aare Muhammadu Buhari to wa ni Londonu bayii, yo Daura bi eni yo jiga latari bi awon DSS naa, pelu ajosepo awon olopaa, se da si ile igbimo asofin ni Abuja, ti won duro tibon-tibon, ti won ko si je ki awon asofin o wole.
Koda, a gbo pe okunrin jeeje abiwa kunkun naa tip e Oga Agba awon olopaa, Abubakar Idris, si ipade pajawiri kan. O fe ki o so ti enu re.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Nàìjíríà sì nílò Ọbásanjọ́ fún ẹkọ́, ọgbọ́n àti ìmọ̀ láti tukọ̀ orílẹ̀-èdè yìí- Buhari

Nàìjíríà sì nílò Ọbásanjọ́ fún ẹkọ́, ọgbọ́n àti ìmọ̀ láti tukọ̀ orílẹ̀-èdè yìí- Buhari Fẹ́…