Home iroyin N ko tii mo eni yoo di olori Redeemed Church leyin mi – Pastor Adeboye
iroyin - August 7, 2018

N ko tii mo eni yoo di olori Redeemed Church leyin mi – Pastor Adeboye

Adari agba fun ijo Redeemed Christian Church of God, Pastor E. A. Adeboye, ti so pe ki awon eniyan to n so pe oun ti daruko eni kan gege bii eni ti yoo di olori soosi naa leyin oun dekun oro aheso.
O ni iru awon eniyan bee ni lati ni suuru digba ti Olorun yoo fi ha noun eni ti yoo di adari leyin ti oun.
O so lasiko isin ni ojo Sunday pea won kan tile n so pe oludasile Living Faith Church Worldwide, Bisoobu David Oyedepo, ni oun yoo gbe asia soosi Ridiimu le lowo.
O ni won so eyi latari bi awon se sun mo ara won pekipeki.
Alagba Adeboye ni eyi ko ri bee, ati pe ki awon alaheso lo ree simido.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Igboho àtàwọn adarí OPC bẹ Aarẹ Ọ̀nà Kakanfo ilẹ̀ Yoruba wò

Igboho àtàwọn adarí OPC bẹ Aarẹ Ọ̀nà Kakanfo ilẹ̀ Yoruba wò Ọrẹ Òtítọ́jù Aja-fẹtọọ’m…