Home Ọ̀RỌ̀-ÒSÈLÚ Atiku ju bombu lu Ebora Owu, o ni anikanjopon lo n da Obasanjo laamu
Ọ̀RỌ̀-ÒSÈLÚ - August 7, 2018

Atiku ju bombu lu Ebora Owu, o ni anikanjopon lo n da Obasanjo laamu

Abi otito ni pe eni to beere oro lo fe idi re gbo? Abi otito ni pe isoro nigbesi, isunkunsi ni igbete gan-n-gan?
Gege bee lo ti ri ni okan oloselu ti a mo si Alhaji Atiku Abubakar.
Ni idahun si ohun ti Aaare ana, Oloye Olusegun Obasanjo, so lori erongba Atiku lati di Aare Naijiria lasiko ibo to n bo, Atiku ti so fun un pe iwa imotara eni nikan lo n da baba ti won tun n pe ni Ebora Owu laamu.
Ninu oro ti Obasanjo so si Atiku, o ni oun ko le se atileyin fun lati di Aare rara nitori awon iwa aidara kan to ti se si oun lowo. O ni pelu ohun ti oun mo, Olorun ko ni fori jin oun ti oun bat un lo satileyin fun un.
Sugbon ninu atejade kan ti akowe ipolongo ibo Atiku, Ogbeni Segun Sowunmi, gbe jade, o ni bi Obasanjo ba ni wahala kankan pelu Olorun, aarin oun at Olorun naa lo wa. Fun idi eyi, Atiku ro o pe ki o wona lati pari ija naa pelu Olorun.
O ni ohun kan to ba Obasanjo je nip e loju ti ara re, oun nikan lo mo; oun nikan lo dara.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Àwọn òṣìṣẹ́, Shoprite, bẹ̀rẹ̀ ìfẹ̀hónúhàn káàkiri àwọn ìpínlẹ̀ kan ní Nàìjíríà.

Àwọn òṣìṣẹ́, Shoprite, bẹ̀rẹ̀ ìfẹ̀hónúhàn káàkiri àwọn ìpínlẹ̀ kan ní Nàìjíríà. Orẹ Òtítọ́…