Home Ọ̀RỌ̀-ÒSÈLÚ Defection di taja-teran: Akpabio n lo APC, Senito n lo APC ni Ebonyi, awon komisanna fe lo PDP l’Ondo
Ọ̀RỌ̀-ÒSÈLÚ - August 6, 2018

Defection di taja-teran: Akpabio n lo APC, Senito n lo APC ni Ebonyi, awon komisanna fe lo PDP l’Ondo

O jo pe oro ijoba tiwa-n-tiwa (democracy) ti wa fe di yeye patapata ni Naijiria o.
Bee, bi awon oloselu se n koja si egbe oselu kan si omiran ti di taja-teran.
Leyin ti awon Bukola Saraki ti bere ere onise naa, opo awon akegbe won miran lo ti gori itage.
Eyi to pabambari ju nibe ni ti Senito Goodswill Akpabio to tinu PDP bo sinu APC.
Bayii, a gbo pea won komisanna kan kan fe fi APC sile lo si PDP, nigba ti Senito kan ni ipinle Ebonyi ti n ko awon oloselu miran sodi lati PDP lo si APC.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Àwọn òṣìṣẹ́, Shoprite, bẹ̀rẹ̀ ìfẹ̀hónúhàn káàkiri àwọn ìpínlẹ̀ kan ní Nàìjíríà.

Àwọn òṣìṣẹ́, Shoprite, bẹ̀rẹ̀ ìfẹ̀hónúhàn káàkiri àwọn ìpínlẹ̀ kan ní Nàìjíríà. Orẹ Òtítọ́…