Home Ọ̀RỌ̀-ÒSÈLÚ Ambode femi imoran han si ijoba apapo
Ọ̀RỌ̀-ÒSÈLÚ - August 6, 2018

Ambode femi imoran han si ijoba apapo

Gomina Akinwunmi Ambode femi imoore han si ijoba Apapo bo se bere ise lori oko oju irin lati ilu Apapa titi de Ibadan ati oju ona lati Apapa kan naa titi de ilu Osodi.

Gomina ipinle Eko tun dupe lowo awon minisita bii Ogbeni Babatunde Fasola ati Ogbeni Rotimi Amechi fun akitiyan won lori bi iya ko se ni je awon ara ipinle Eko.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Igboho àtàwọn adarí OPC bẹ Aarẹ Ọ̀nà Kakanfo ilẹ̀ Yoruba wò

Igboho àtàwọn adarí OPC bẹ Aarẹ Ọ̀nà Kakanfo ilẹ̀ Yoruba wò Ọrẹ Òtítọ́jù Aja-fẹtọọ’m…