N ko tii setan lati fe iyawo miran bayii – Oko Mercy Aigbe
Okunrin ti Mercy Aigbe fi sile, Ogbeni Lanre Gentry, ti so pe oun to tii setan lati fe iyawo miiran.
O ti fee to odun kan ti Mercy ti ko jade nile re, to si ti n da gbe.
Ija nla kan lo be sile larin won, ti Mercy si so pe Gentry maa n na oun ni alupamoku.
Koda, kandu-kandu ni oju obinrin naa wu nigba naa.
Nigba ti Gentry wa n soro lori ajosepo aarin won, o ni awon si maa n soro.
O fi kun pea won ko tii tu igbeyawo naa ka ni kootu.
Gentry ni idi niyi ti oun ko fi le se igbeyawo miiran bayii.
Àwọn òṣìṣẹ́, Shoprite, bẹ̀rẹ̀ ìfẹ̀hónúhàn káàkiri àwọn ìpínlẹ̀ kan ní Nàìjíríà.
Àwọn òṣìṣẹ́, Shoprite, bẹ̀rẹ̀ ìfẹ̀hónúhàn káàkiri àwọn ìpínlẹ̀ kan ní Nàìjíríà. Orẹ Òtítọ́…