Iyawo gun baale re lobe pa n’lu Eko
Ajalu nla tun ti sele laarin lokolaya kan ni ilu Eko.
Arakunrin kan ti oruko re n je Olumide Ayeni ni iyawo re ti gun lobe pa, nitori pe o ri obinrin miiran pelu re.
Lenu ojo meta yii, ajalu to n sele ninu igbeyawo kii se keremi.
Bi oko se n pa aya ni iyawo n pa oko re, to si n sele laarin idile olowo ati ti otosi.
Obinrin naa to pa Olumide Ayeni ti wa pelu awon olopaa Eko bayii.
Nàìjíríà sì nílò Ọbásanjọ́ fún ẹkọ́, ọgbọ́n àti ìmọ̀ láti tukọ̀ orílẹ̀-èdè yìí- Buhari
Nàìjíríà sì nílò Ọbásanjọ́ fún ẹkọ́, ọgbọ́n àti ìmọ̀ láti tukọ̀ orílẹ̀-èdè yìí- Buhari Fẹ́…