Awon emewa Fayemi n fi Fayose se yeye
Awon omoleyin Gomina to n bo ni Ekiti, Dokita Kayode Fayemi, si tubo n fi Gomina Ayodele se yeye bayii ni o.
Won ni nibo lo wa gan-an?
Gege bi won se n so lori Facebook, won ni awon ko ri Fayose ko maa se akikanju to ti maa n se tele ni PDP. Won ni bi awon olori PDP se n se yata-yoto lori awon omo egbe APC ti won sa lo si PDP, awon ko tie ri Fayose nibe. Won ni se o ti re e ni?
Lara awon ti won fi gomina naa pa miidin ni Ogbeni Segun Dipe ati Mojeed Jamiu.
Àwọn òṣìṣẹ́, Shoprite, bẹ̀rẹ̀ ìfẹ̀hónúhàn káàkiri àwọn ìpínlẹ̀ kan ní Nàìjíríà.
Àwọn òṣìṣẹ́, Shoprite, bẹ̀rẹ̀ ìfẹ̀hónúhàn káàkiri àwọn ìpínlẹ̀ kan ní Nàìjíríà. Orẹ Òtítọ́…