Home LÁGBO ÀRÍYÁ Ali Baba n ba Pastor Kasali fa surutu
LÁGBO ÀRÍYÁ - August 4, 2018

Ali Baba n ba Pastor Kasali fa surutu


Oga alawada stand up comedian, Ali Baba, ti se atako ojise Olorun kan, Pasito Yomi Kasali, to ni ko dara bi awon olori ijo se maa n pe awon alawada si soosi lati sere fun awon omo ijo.
Pasito Kasali ni soosi kii se ile komedi, to si tun bu enu ate lu bi awon alawada se maa n fi awon pasito se yeye ninu awon itan ti won n so.
Sugbon, Yoruba ni bi owe ba jo owe eni, a maa n fesi le e ni. Bi a ko ba fesi, eru ija lo n ba ni.
Eyi lo difa fun Ali Baba to fi so fun Pasito Kasali pe ko si ohun ti ko ba ofin mu ninu ki awon onikomedi maa sere ni soosi.
O ni aseju ni ko dara. O wa so fun Pasito Kasali pe ti a ba ni ki onikomedi ma wo soosi, awon onijibiti ati odaran miiran ti won n gba idamewaa lowo won nko?

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Igboho àtàwọn adarí OPC bẹ Aarẹ Ọ̀nà Kakanfo ilẹ̀ Yoruba wò

Igboho àtàwọn adarí OPC bẹ Aarẹ Ọ̀nà Kakanfo ilẹ̀ Yoruba wò Ọrẹ Òtítọ́jù Aja-fẹtọọ’m…