O ga ju! Pastor fun asewo meji ni 7 million naira!
Ise asewo ti gbe awon obinrin meji kan debi ire o.
Bi o tile je pe sanmooni lo so won di asewo, kinni naa ti so won di milonia.
Olori ijo soosi ti a mo si Mercy City lo se won lore naa, nigba ti won lo sibi ipago re.
Oruko awon obinrin naa ni Egbiremonnien Mary ati Jennifer Airel, nigba ti Ojise Olorun naa n je Jeremiah Fufeyin.
Leyin ti awn obinrin naa jewo, ti won si so pe awon ko ni pada si ise nabi mo ni Fufeyin gbe ow naa fun won, pe ki won lo fi bere ise, ki won si maa gbe aye tuntun.
Ààrẹ Buhari àti igbákejì rẹ̀, Yemi Osinbajo ti gba abrẹ́rẹ́ àjẹsáèra Kófíìdì-19.
Ààrẹ Buhari àti igbákejì rẹ̀, Yemi Osinbajo ti gba abrẹ́rẹ́ àjẹsáèra Kófíìdì-19. Ọrẹ Òtítọ…