Home LÁGBO ÀRÍYÁ Chioma, ololufe Davido to gba G Wagon, ko tii mo moto wa
LÁGBO ÀRÍYÁ - August 2, 2018

Chioma, ololufe Davido to gba G Wagon, ko tii mo moto wa


Olorun tobi loba. Onikaluku pelu adanwo tie.
Olorun le fun eni kan ni bata ko ma ni ese ti yoo wo bata naa si. Awon miiran a ni ese, won ko ni rowo bata.
Bakan naa, opo eniyan lo mo bi won se n wa moto, ti ko rowo ra keeke, opo eniyan lo row ra moto ti ko si mo o wa.
Eyi lo difa fun arabinrin arewa kan to n je Chioma, iyawo gbajugbaja akorin ti a mo si Davido.
Laipe yii ni Davido ra moto G Wagon kan fun un, ti owo re le to ogota milionu naira.
Sugbon lati igba naa, Chioma ko tii maa wa moto yen. Eyi lo fa a
Eyi lo fa bi awn eniyan kan se n beere pe kin lo de ti ko tii maa wa moto naa.
Nigba ti Davido n fesi lori eleyii, o ni Chioma ko tii mo moto wa ni.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ààrẹ Buhari àti igbákejì rẹ̀, Yemi Osinbajo ti gba abrẹ́rẹ́ àjẹsáèra Kófíìdì-19.

Ààrẹ Buhari àti igbákejì rẹ̀, Yemi Osinbajo ti gba abrẹ́rẹ́ àjẹsáèra Kófíìdì-19. Ọrẹ Òtítọ…