Awon Fulani darandaran fiya nla je Funke Adesiyan
Osere fiimu, Funke Adesiyan, ti se alaye bi awon Fulani onimaalu se fiya nla je e, debi pe osibitu lo gba a sile.
Kii se pe won na Funke ni tabi pe won sa a ni ada. Dipo bee, awon darandaran naa da maluu sinu oko water melon to da, ti won sib a a je patapata.
Arabinrin naa ko owo nla sori oko water melon naa, o ba awon oyinbo nla sowo po, sugbon nigba ti asiko to lati kore oko, nibi to ti n reti owo nla, awon Fulani naa da eran wonu oko re.
Iléeṣé ológùn ti sìnkú àwọn akọni tó bá ìjàmbá ọkọ̀ Bàálù lọ ní Abuja
Iléeṣé ológùn ti sìnkú àwọn akọni tó bá ìjàmbá ọkọ̀ Bàálù lọ ní Abuja Ọrẹ Òtítọ́jù Àwáyé è…