Home Ọ̀RỌ̀-ÒSÈLÚ Alaimoore ni buoda mi – Gbemisola, aburo Saraki
Ọ̀RỌ̀-ÒSÈLÚ - August 1, 2018

Alaimoore ni buoda mi – Gbemisola, aburo Saraki


Gbemisola Saraki, to je aburo Aare Ile Igbimo Asofin Agba, Dokita Bukola Saraki, ti so pe alaimoore ati odale eniyan ni.
O ni eyi lo fa a ti Bukola fi kuro ninu egbe APC to si pada si PDP.
Gbemisola ni igbese ti egbon oun gbe naa ti mu opin de ba itesiwaju re ninu oselu.
Gege bi o se so, o ni oun setan lati dije fun ipo ile igbimo asofin agba, leyii to tumo si pe yoo figa gbaga pelu egbon re.
Gbemisola tun fi kun un pe gbongbon ni oun wa leyin Aare Muhammadu Buhari, lori aayan ati pada si ipo re lodun to n bo.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Igboho àtàwọn adarí OPC bẹ Aarẹ Ọ̀nà Kakanfo ilẹ̀ Yoruba wò

Igboho àtàwọn adarí OPC bẹ Aarẹ Ọ̀nà Kakanfo ilẹ̀ Yoruba wò Ọrẹ Òtítọ́jù Aja-fẹtọọ’m…