Home Orisirisi Bolaji Abdullahi, awon asofin metalelogun tele Bukola Saraki lo si PDP
Orisirisi - August 1, 2018

Bolaji Abdullahi, awon asofin metalelogun tele Bukola Saraki lo si PDP


Opo awon oloselu nla to wa ni APC tele ni Ipinle Kwara ni won ti n tele Dokita BUkola Saraki lo si egbe PDP o.
Ana ni Saraki ati Gomina Ipinle naa, Alhaji Abdullahi Fatai, pada si PDP.
Bayii, Alukoro egbe APC, Alagba Bolaji Abdullahi, naa ti kuro ni egbe naa. O ti lo ba Saraki ni PDP.
Bakan naa, awon asofin metalelogun ni iinle naa ni won ti lo si PDP.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Nàìjíríà sì nílò Ọbásanjọ́ fún ẹkọ́, ọgbọ́n àti ìmọ̀ láti tukọ̀ orílẹ̀-èdè yìí- Buhari

Nàìjíríà sì nílò Ọbásanjọ́ fún ẹkọ́, ọgbọ́n àti ìmọ̀ láti tukọ̀ orílẹ̀-èdè yìí- Buhari Fẹ́…