Home iroyin Oga agba ijoba ibile ku sinu kanga!
iroyin - July 31, 2018

Oga agba ijoba ibile ku sinu kanga!

Ti won ba pe eniyan ni ‘Bamisaye’, ohun ti eniyan tyoo maa ro nipa eni naa ni pe yoo je eni to feran ki onikaluku maa gbe aye ni alaafia, ki emi onikaluku o gun daadaa.
Sugbon eyi ko ri bee fun okunrin kan ti oruko re n je Michael Kayode Bamisaye o.
Okunrin naa ti o je oga agba fun eto isuna ni Ise/Orun Ekiti Local Government, ni Ise-Ekiti, ti pa ara re nipa bibe sinu kanga.
Koda, won ni o ti koko po omi po mo simenti, to si gbe e mu ki o to lo be sinu kanga.
Lojo ti isele yii sele, a gbo pe Bamisaye ko se bi eni ti inu re ko dun. O ba iyawo ati awon omo re sere. Leyin naa lo yo jade sita, ti iyawo re sib a a ninu kanga leyin-o-reyin.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Iléeṣé ológùn ti sìnkú àwọn akọni tó bá ìjàmbá ọkọ̀ Bàálù lọ ní Abuja

Iléeṣé ológùn ti sìnkú àwọn akọni tó bá ìjàmbá ọkọ̀ Bàálù lọ ní Abuja Ọrẹ Òtítọ́jù Àwáyé è…