Home Orisirisi Idi ti emi ati Genevieve kii fii se ore timotimo – Omotola
Orisirisi - July 31, 2018

Idi ti emi ati Genevieve kii fii se ore timotimo – Omotola


Gbajugbaja osere fiimu, Genevieve Nnaji, ti soro lori idi ti oun ati akegbe re, Gnevieve Nnaji, kii fii se ore korikosun.
Omotola ko so pe ota ni awon o, ko so pe oun ni ija kan pato pelu Genevieve, sugbon o jewo pea won ko sun mo ara won pekipeki, bi o tile je pe won ti jo wa ni idi ise fiimu, ojo pe.
Lasiko iforowanilenuwo kan pelu awon ololufe re lori Instagram, eni kan bi Omotola leere lori kin lo fa a ti oun Genevieve ko fi sun mo ara won.
Idahun soki ti Omotola fun eni naa ni pe, ‘Kin lo fa a tie mi ati iwo kii fii se ore timotimo?:
Eyi tumo si pe ibeere lo fi dahun ibeere ti won bi i, to si je pe ibeere naa loyun gidi.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Igboho àtàwọn adarí OPC bẹ Aarẹ Ọ̀nà Kakanfo ilẹ̀ Yoruba wò

Igboho àtàwọn adarí OPC bẹ Aarẹ Ọ̀nà Kakanfo ilẹ̀ Yoruba wò Ọrẹ Òtítọ́jù Aja-fẹtọọ’m…