Home Orisirisi Eru ko bodo – Buhari
Orisirisi - July 31, 2018

Eru ko bodo – Buhari

Aare orileede yii, Mohammadu Buhari n da gbogbo awon ti o n fi egbe sile lohun pe, eru ko bodo ni oun, eni ti yoo wo odo nikan ni ominu n ko.

Awon oniroyin ni o ye ki eru ti maa ba Aare Buhari nipa bi gomina se n fegbe sile, ti Aare ile igbimo asofin ati awon asofin kan n fegbe sile, koda a tun ri asoju orileede yii ni South Africa ti oun naa tun kowe fegbe sile.

Aare Buhari ni ti Olorun ba ti wa leyin eniyan, o ju egberun asofin ati asoju lo. O fi da awon ara ilu ati awon to le fara da egbe to n sooto loju pe didun ni osan egbe naa maa so ni igbeyin.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Iléeṣé ológùn ti sìnkú àwọn akọni tó bá ìjàmbá ọkọ̀ Bàálù lọ ní Abuja

Iléeṣé ológùn ti sìnkú àwọn akọni tó bá ìjàmbá ọkọ̀ Bàálù lọ ní Abuja Ọrẹ Òtítọ́jù Àwáyé è…