Home iroyin Melaye gbe omiran yo, o ni ori igi ni oun wa fun wakati mokanla
iroyin - July 30, 2018

Melaye gbe omiran yo, o ni ori igi ni oun wa fun wakati mokanla

Senito Dino Melaye ti so pe kii se pe won ji oun gbe nigba ti won ko ri oun nita gbangba laipe yii o.
O ni dipo bee, oun sa asala fun emi oun ni nigba ti awon agbanipa – hired assassins – kan fe pa oun.
O ni oju ona Abuja ni won ti dena de oun, sugbon oun dogbon sa mo won lowo.
O ni inu igbo ti oun sa si, ti won ti bere si le oun, ni oun ti dogbon gun ori igi kan, ti oun si wa nibe fun wakati mokanla gbako.
Oro ti Melaye so naa ran opo eniyan leti awon itan D. O. Fagunwa ati oun to maa n sele ninu fiimu Nollywood.
Nitori idi eyi, won ko gba Melaye gbo rara.
Inui we iroyin Premium Times ni asofin naa ti se alaye yii, lasiko iforo wa ni lenu wok an.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ààrẹ Buhari àti igbákejì rẹ̀, Yemi Osinbajo ti gba abrẹ́rẹ́ àjẹsáèra Kófíìdì-19.

Ààrẹ Buhari àti igbákejì rẹ̀, Yemi Osinbajo ti gba abrẹ́rẹ́ àjẹsáèra Kófíìdì-19. Ọrẹ Òtítọ…