Home Orisirisi Leyin odun mefa, awon omo Iyabo Ojo foju kan baba won
Orisirisi - July 30, 2018

Leyin odun mefa, awon omo Iyabo Ojo foju kan baba won

Idunnu ti subu lu ayo nile onifiimu ti a mo si Iyabo Ojo.
Awon ti inu won n dun ju ni omo re mejeeji, Priscilia ati Festus.
Idi ni pe awon mejeeji fi oju kan baba won leyin odun mefa ti won ti ri ara won gbeyin.
Ni odun 1999 ni Iyabo Ojo se igbeyawo pelu baba awon omo naa.
Won bimo akoko ni odun naa, ti won si bi ekeji ni 2001.
Ko pe si asiko yii ni ede aiyede to de, ti awon mejeeji si ko ara won sile.
Nigba ti awon omo mejeeji n soro lori ipade nla naa pelu baba won won ni inu awon dun de gongo.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Àwọn òṣìṣẹ́, Shoprite, bẹ̀rẹ̀ ìfẹ̀hónúhàn káàkiri àwọn ìpínlẹ̀ kan ní Nàìjíríà.

Àwọn òṣìṣẹ́, Shoprite, bẹ̀rẹ̀ ìfẹ̀hónúhàn káàkiri àwọn ìpínlẹ̀ kan ní Nàìjíríà. Orẹ Òtítọ́…