Home iroyin Ayo oniwa tutu pokunso ni Akure
iroyin - July 30, 2018

Ayo oniwa tutu pokunso ni Akure

Nigba ti awon olopaa Ipinle Ondo si n sise lori okunrin kan to n je Adeyemi Alao, ti won won lo pa omo yunifasiti kan, Khadijat Lasisi, okunrin miiran tun ti da kun wahala won o.
Eni naa ni oruko re n je Ayo Paul, eni ti o pa ara re nipa bi o se pokunso lojo Satide ijeta.
Isele naa ya lanloodu ati awon alabagbepo Ayo lenu pupo tori won ni eni to niwa tutu bi adaba ni nigba aye re.
Alukoro awon olopaa ipinle naa, Alagba Femi Joseph, ni loooto ni isele naa sele, ti awon si ti bere ise iwadii lori ohun to je ki Ayo gbemi ara re.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Iléeṣé ológùn ti sìnkú àwọn akọni tó bá ìjàmbá ọkọ̀ Bàálù lọ ní Abuja

Iléeṣé ológùn ti sìnkú àwọn akọni tó bá ìjàmbá ọkọ̀ Bàálù lọ ní Abuja Ọrẹ Òtítọ́jù Àwáyé è…