Home Ọ̀RỌ̀-ÒSÈLÚ APC n fi oju Ortom wina
Ọ̀RỌ̀-ÒSÈLÚ - July 30, 2018

APC n fi oju Ortom wina

O jo pe orin ti egbe APC n ko fun Gomina Ipinle Benue, Samuel Ortom, bayii ni pe eni to ba se ohun ti eni kan ko se ri, oju re a ri ohun ti eni kan ko ri ri.
Boya orin naa si nip e bi adie bad a mi loogun nu, maa fo o leyin.
Idi ni pe leyin ojo bii merin ti Ortom ti fi egbe naa sile lo si PDP, orisiirisii isele ti o n ko laasigbo ba a ni o ti n sele.
Lonii, awon asofin omo egbe APC mejo gbiyanju ati yo Ortom gege bii gomina.
Gege bi iroyin si ti so, won ni awon agbofinro ko je ki awon asofin mejilelogun ti kiba gba a sile wonu ile igbimo asofin ni Makurdi.
Bakan naa, ajo EFCC ti fie sun sise owo to je bilionu mejilelogun – billion naira – kan Ortom.
Eyi fa a ti gomina naa fi n figba ta, to si so pe iwa buruku ni egbe APC n hu.
O ni anjuwon loro to wa nile yii ti ko see wi lejo, ti ija ilara ko si tan boro.
O ni abalajo ti Aare Orile-ede America, iyen Donald Trump, fi pe orile-ede Naijiria ni ile igbe – shithole country.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Nàìjíríà sì nílò Ọbásanjọ́ fún ẹkọ́, ọgbọ́n àti ìmọ̀ láti tukọ̀ orílẹ̀-èdè yìí- Buhari

Nàìjíríà sì nílò Ọbásanjọ́ fún ẹkọ́, ọgbọ́n àti ìmọ̀ láti tukọ̀ orílẹ̀-èdè yìí- Buhari Fẹ́…