Home Ọ̀RỌ̀-ÒSÈLÚ Awon omo Naijiria ni opuro buruku ni Dino Melaye
Ọ̀RỌ̀-ÒSÈLÚ - July 29, 2018

Awon omo Naijiria ni opuro buruku ni Dino Melaye

Opolopo omo Naijiria ni won ti laali Senito Dino Melaye lori bo se so pea won kan ji oun gbe.
Nigba ti won n fesi lori bi o se so pe oun sa kuro lodo awon ajinigbe, won ni alainikan-an-se ni, ati eni to n tan ara re to ni oun n tan eniyan.
Awon omo Nijiria bii Remmy Olamide, Juliet Clement ati Yomi David ni Melaye ro pe gbogbo omo Naijiria go ti won fenu hora ni.
Awon kan ni yoo jiya re lasiko ibo 2019.
Sugbon sa o, a si ri awon kan ti won n kan saara si i lori ero alatgaba ti won ti n gba a bi eni gba igba oti.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Iléeṣé ológùn ti sìnkú àwọn akọni tó bá ìjàmbá ọkọ̀ Bàálù lọ ní Abuja

Iléeṣé ológùn ti sìnkú àwọn akọni tó bá ìjàmbá ọkọ̀ Bàálù lọ ní Abuja Ọrẹ Òtítọ́jù Àwáyé è…