Home ERÉ ÌDÁRAYÁ Asisat Oshoala ra ile nla fun awon obi re
ERÉ ÌDÁRAYÁ - July 29, 2018

Asisat Oshoala ra ile nla fun awon obi re

Omobinrin agbaboolu fun Naijiria ati Liverpool, Asisat Oshoala, ti ra ile nla kan fun awon obi re.
Adugbo Costain ni ilu Eko ni ile gagara naa wa.
Olorun ti se bebe ninu aye Asisat, nipa ebun boolu gbigba ti o ni, ti on naa si ti n gba owo ribiribi ni ile okeere.
Nigba to n fesi lori ile naa, Asisat se ‘Alliamudulilahi’. O ni oun ni omo kekere to ni Olorun rabata.
Oro ki sibe!

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Nàìjíríà sì nílò Ọbásanjọ́ fún ẹkọ́, ọgbọ́n àti ìmọ̀ láti tukọ̀ orílẹ̀-èdè yìí- Buhari

Nàìjíríà sì nílò Ọbásanjọ́ fún ẹkọ́, ọgbọ́n àti ìmọ̀ láti tukọ̀ orílẹ̀-èdè yìí- Buhari Fẹ́…