Home Orisirisi Ambode dun Daddy Showkey ninu
Orisirisi - July 29, 2018

Ambode dun Daddy Showkey ninu

Gomina Ipinle Eko, Ogbeni Akinwunmi Ambode, ti mu ki inu akorin Galala, Daddy Showkey, maa dun sinkin bayii.
Eyi waye nipa bi ijoba Eko se setan lati se awon ise akanse kan ni agbegbe Ajegunle, nibi ti Daddy Showkey ati opo alariya miiran tedo si.
Laipe yii ni Daddy Showkey ke gbajare si Gomina Ambode, to ta a lolobo pe ko jowo bu oju aanu wo Ajegunle, bi o ti se n se kaakiri ipinle naa.
Ni bayii, Ambode ti mu u da Ajegunle loju pe afefe Itesiwaju Ipinle Eko yoo fe lu won ni waransasa.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Igboho àtàwọn adarí OPC bẹ Aarẹ Ọ̀nà Kakanfo ilẹ̀ Yoruba wò

Igboho àtàwọn adarí OPC bẹ Aarẹ Ọ̀nà Kakanfo ilẹ̀ Yoruba wò Ọrẹ Òtítọ́jù Aja-fẹtọọ’m…