Home LÁGBO ÀRÍYÁ Aisha, Beautiful Nubia ba Kabirah Arapa se ajoyo ojo ibi
LÁGBO ÀRÍYÁ - Orisirisi - July 29, 2018

Aisha, Beautiful Nubia ba Kabirah Arapa se ajoyo ojo ibi

Opo eniyan pataki ni won n ki osere fiimu, Kabirah Kafidipe, se eye ojo ibi te to n waye lonii.
Pelu orin ope ni Kabirah fi kede ojo ibi naa lori Instagram, pelu awon foto to rewa, ati awon gbolohun arojinle lori ajosepo re pelu Olorun, awon obi ati molebi re, ti ko si yo ore ati ojulumo seyin.
Bi o se n se eyi naa ni egbon re, Aisha Kafidipe, ti oun naa je osere, akorin ati olukotan, n ki i ni mesan-an mewaa.
Aisha ni oloriire omo ni Kabirah, o ni alafehinti ati olubadamoran oun lo tun je.
Aisha tun ti wa gbe fidio kan sori ate Instagram, nibi ti orin aladun Beautiful Nubia ti n lo labe awon foto alarabara Kabirah ti n gori ara won.
Ni pataki, a ri Kabirah nigba to wa ni omo pinnisin, ti baba re, Alhaji Kafidipe, ti n ba a sere.
Leyin wi pe foto naa tun ran wa leti pe omo kii pe dagba – bii orin Sikiru Ayinde Barrister – o tun fun Kabirah laaye lati kan saara si baba to je oloko to tu u was aye.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Iléeṣé ológùn ti sìnkú àwọn akọni tó bá ìjàmbá ọkọ̀ Bàálù lọ ní Abuja

Iléeṣé ológùn ti sìnkú àwọn akọni tó bá ìjàmbá ọkọ̀ Bàálù lọ ní Abuja Ọrẹ Òtítọ́jù Àwáyé è…