Home LÁGBO ÀRÍYÁ Kabirah Araparegan-gan se waasi lori esan
LÁGBO ÀRÍYÁ - July 28, 2018

Kabirah Araparegan-gan se waasi lori esan

Osere fiimu, Kabirah Kafidipe, ti so idi pataki ti a ko gbodo fi maa gba esan lowo awon to ba se wa.
Ninu waasi to maa n se ni idaji idaji lori ero alatgba Instagram, o ni esan ko dara rara, tori o ye ki omo Mumini maa fi gbogbo oro le Olorun lowo ni.
Kabirah ni ona to dara ju lati gbesan ni ki eniyan ma gbesan rara.
O ni ko si bi nnkan se le dun eniyan to, nigba to bay a, iwosan yoo de ba ara ati okan iru eni bee.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Iléeṣé ológùn ti sìnkú àwọn akọni tó bá ìjàmbá ọkọ̀ Bàálù lọ ní Abuja

Iléeṣé ológùn ti sìnkú àwọn akọni tó bá ìjàmbá ọkọ̀ Bàálù lọ ní Abuja Ọrẹ Òtítọ́jù Àwáyé è…