Owo olopaa otelemuye te okunrin to ni moto ajagbe ejo to gbina ni Otedola Bridge
Igbese ti awon olopaa otelemuye Panti, ni Ipinle Eko, n gbe lati se awrai direba to wa tanka to gbina ni biriiji Otedola, ni Berger, Ipinle Eko, ti n so eso rere.
Bi won ko tie tii ri direba naa, owo won tit e eni to ni moto naa.
Eni naa ti oruko re n je Hassan Yusuff Maiwake ni a gbo pe won gbamu ni Kano.
O ti wa n ran awon olopaa lowo lori aayan won lati ri direba naa, se ti a ba fa gburu, gburu a fagbo.
Ààrẹ Buhari àti igbákejì rẹ̀, Yemi Osinbajo ti gba abrẹ́rẹ́ àjẹsáèra Kófíìdì-19.
Ààrẹ Buhari àti igbákejì rẹ̀, Yemi Osinbajo ti gba abrẹ́rẹ́ àjẹsáèra Kófíìdì-19. Ọrẹ Òtítọ…