Iyawo Ayefele soro lori asiri ife to wa laarin won
Bi o tile je pe gbajugbaja ni Yinka Ayefele, opo eniyan ni ko mo iyawo re, debi pe won a mo oruko re. Bee, eegun moni bi eniyan ko mo o.
Ni bayii, obinrin naa ti oruko re n je Temitope ti soro lori iru eni to je ati idi ti oun fi diro mo Yinka Ayefele sinsin.
Omo bibi ilu Ibadan ni Temitope, ti baba re, Alagba Mathew Oladokun Fawusi, si je ojogbon, iyen professor.
Omo Ibadan ponbele ni obinrin naa; ile Laamo ni won bi i si, Bodija lo si ti dagba.
Iyaafin Temitope so pe ni odun 1996 ni oun ati Ayefele pade. Odun 1997 ni akorin naa ni ijamba moto, to je pe Olorun lo yo o.
Obinrin naa wa se alaye pe bi o tile je pe nnkan le koko fun awon nigba naa, oun duro ti Ayefele titi di oni tori un ti se ipinnu lati lo gbogbo aye oun pelu re ko to dip e ijamba moto waye.
O ni yefele jealakikanju okunrin, ti kii sii fe fi ise sere.
Iléeṣé ológùn ti sìnkú àwọn akọni tó bá ìjàmbá ọkọ̀ Bàálù lọ ní Abuja
Iléeṣé ológùn ti sìnkú àwọn akọni tó bá ìjàmbá ọkọ̀ Bàálù lọ ní Abuja Ọrẹ Òtítọ́jù Àwáyé è…