Home iroyin Saraki ni ko pon dandan ki oun lo ri Oga Olopaa Idris lori oro ole to ja ni Offa
iroyin - Orisirisi - July 26, 2018

Saraki ni ko pon dandan ki oun lo ri Oga Olopaa Idris lori oro ole to ja ni Offa

Aare Ile Igbimo Asofin Agba, Dokita Bukola Saraki, ti so pe ko pon dandan ki oun lo ri Oga Agba awon olopaa, Abubakar Idris mo, lori oro awon igara olosa to ja ni ilu Offa, eyi ti won ni ki oun wa ri won fun.
Gege bi oro ti Akowe Iroyin Agba fun Saraki, Alhaji Yusuph Olaniyonu, se so, Saraki ti ko leta miiran si Idris, nibi to tun ti so pe oun ko mo awon ole naa ri.
O ni fun idi eyi, ko ni lati sese maa da agbada lo sibe mo, tori oun to ye ko so ni ago olopaa naa lo ti wa ninu leta naa.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Igboho àtàwọn adarí OPC bẹ Aarẹ Ọ̀nà Kakanfo ilẹ̀ Yoruba wò

Igboho àtàwọn adarí OPC bẹ Aarẹ Ọ̀nà Kakanfo ilẹ̀ Yoruba wò Ọrẹ Òtítọ́jù Aja-fẹtọọ’m…