Home LÁGBO ÀRÍYÁ Ronke Oshodi Oke seranti Alaran
LÁGBO ÀRÍYÁ - July 26, 2018

Ronke Oshodi Oke seranti Alaran

Odun mejila leyin iku osere onikomedi, Mufutau Aladokun, ti gbogbo eniyan mo si Alaran, onifiimu ti a mo si Ronke Oshodi Oke ti seranti re o.
Ronke se sadnkaata fun Alaran, to si so pe oun lo je ki oun di eni pataki ninu ise fiimu.
Ninu arojinle kan ti Ronke Osodi Oke se, o ni nigba ti oun ko mo eyi ti oun yoo se, to da bi pe nnkan ko fe ni ojutuu fun oun, Alaran lo ni ki oun ma mikan, Olorun yoo se e.
Lori Instagram ti oro yii ti waye, opo eniyan naa lo kan saara si Alaran, ti won si kan saara si Ronke naa, nitori won gba pe kii se afibisoloore.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Àwọn òṣìṣẹ́, Shoprite, bẹ̀rẹ̀ ìfẹ̀hónúhàn káàkiri àwọn ìpínlẹ̀ kan ní Nàìjíríà.

Àwọn òṣìṣẹ́, Shoprite, bẹ̀rẹ̀ ìfẹ̀hónúhàn káàkiri àwọn ìpínlẹ̀ kan ní Nàìjíríà. Orẹ Òtítọ́…